Lydia Ankrah jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ akọkọ, óṣu December ni ọdun 1973. Agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbinrin post gẹgẹbi defender[1].

Lydia Ankrah
Personal information
Ọjọ́ ìbí1 Oṣù Kejìlá 1973 (1973-12-01) (ọmọ ọdún 51)
Playing positionDefender
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
Post Ladies
National team
Ghana women's national football team14(0)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 10 September 2007 (before the 2007 FIFA Women's World Cup)

Àṣeyọri

àtúnṣe
  • Lydia kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agbaye to waye ni ọdun 2003 ati 2007[2].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://www.eurosport.com/football/lydia-ankrah_prs414861/person.shtml
  2. https://www.playmakerstats.com/player.php?id=182363