Mákòókó
Mákòóko jẹ́ ibùgbé àìtọ́ ní 3rd Mainland Bridge tí ó wà ní Èkó. Orí omi ní ìdá mẹ́ta agbègbè yìí wà tí ìyóókù ní orí ilẹ̀. Awọn Egun tí wọ́n kúrò ní ìlú Badagary àti Republic of Benin tí iṣẹ́ wọn jẹ́ pẹja-pẹja..
Mákòókó ni wọ́n máa ń pè ní "Venice of Africa". Èyí ri bẹ́ẹ̀ torí orí omi tí ìɔú náà wà. [1] Iye àwọn ènìyàn ti wọ́n ń gbé ní bẹ̀ jẹ́ 85,840, àmọ́ nínú ìkànìyàn 2007, agbègbè yìí kò sí lára Èkó àmọ́ àwọn ènìyàn tí wọ́n ń gbé ní bẹ̀ pọ̀ ju àwọn agbègbè tó kù ní Èkó.[2]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Soni Methu (24 December 2014). "Postcards from home: documenting Nigeria's floating community". CNN. http://edition.cnn.com/2014/12/24/world/africa/nigeria-makoko-photograph-sulayman-afose/. Retrieved 10 October 2015.
- ↑ This Day (1 May 2009). "Makoko Residents And Their Unwanted Guest". Africa News.