Mátsù Píktsù
Mátsù Píktsù (Àdàkọ:Lang-qu, "Old Peak", pìpè [ˈmɑ.t͡ʃu ˈpix.t͡ʃu]) ni igba iwaju Kolumbia ile Inca to budo si 2,430 metres (7,970 ft) loke ipele okun.[1][2] O budo si oke ebe lori Afonifoji Urubamba ni Peru, to je 80 kilometres (50 mi) ariwaiwoorun Cuzco ninu ibi ti Odo Urubamba gba koja. Opo awon onimo arkeoloji gbagbo pe Machu Picchu je kiko gege bi ile fun oluaye Inca Pachacuti (1438–1472). O je titoksi bi "The Lost City of the Incas",
Historic Sanctuary of Machu Picchu* | |
---|---|
Ibi Ọ̀ṣọ́ Àgbáyé UNESCO | |
Huayna Picchu towers above the ruins of Machu Picchu | |
State Party | Peru |
Type | Mixed |
Criteria | i, iii, vii, ix |
Reference | 274 |
Region** | Latin America and The Caribbean |
Inscription history | |
Inscription | 1983 (Seventh Session) |
Lua error in Module:Location_map at line 363: Minutes can only be provided with DMS degrees for longitude. | |
* Name as inscribed on World Heritage List. ** Region as classified by UNESCO. |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |