Mùhammédù 6k ilẹ̀ Mòrókò

Mohammed VI (Lárúbáwá: محمد السادس‎) ni Oba orile-ede Morocco lowolowo. Won bi ni 21 August 1963, o si gori ite ni July 1999.

Mohammed VI
Reign 23 July 1999 – present (10 years)
Predecessor Hassan II
Spouse Princess Lalla Salma
Issue
Moulay Hassan
Lalla Khadija
Father Hassan II
Mother Lalla Latifa Hammou
Religion Islam