Ọkọ̀ Akérò lórí ilẹ̀
(Àtúnjúwe láti Mọ́tọ́ò Agbègbè)
Ọkọ̀ Akérò jẹ́ Ọkọ̀ ọkan lára àwọn tí àwọn ènìyàn máa ń wọ̀ lọ sí ibikíbi tí wọ́n bá lọ. Àwọn ènìyàn nífẹ̀ẹ́ sí kọ́ ma wọ Ọkọ̀ Akérò gan-an. Bẹ́ẹ̀ náà sì ni àwọn ènìyàn máa ń rà á láti fi ma kó èrò. Àwọn owó tí wọ́n bá rí níbi yìí ni wọ́n máa ń fí bọ́ àwọn ẹbí wọn nílé.[1] [2]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "BU. - Meaning & Definition for UK English". Lexico Dictionaries. Archived from the original on 2022-05-21. Retrieved 2022-05-21. Text "English" ignored (help)
- ↑ "Bus". Wikipedia. 2001-09-07. Retrieved 2022-05-21.