MC Oluomo tí orúkọ rẹ̀ gan-an ń jẹ́ Musiliu Akinsanya (tí wọ́n bí lọ́jọ́ 14 oṣù kẹta ọdún 1975) ni alága-àná ẹgbẹ́ àwọn awakọ̀, National Union of Road Transport Workers ní Ìpínlẹ̀ Èkó.[1][2] Lọ́wọ́lọ́wọ́, òun ni alága yànyàn ti ẹgbẹ́ àwọn awakọ̀, NURTW ni Nigeria.[3] Wọ́n gbàgbọ́ pé òun ni ìpátá ọmọ tó lówó jùlo ni Nigeria.[4][5][6]

MC Oluomo
Ọjọ́ìbíMusiliu Akinsanya
14 Oṣù Kẹta 1975 (1975-03-14) (ọmọ ọdún 49)
Oshodi, Lagos

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Wo ǹkan tó yẹ kí o mọ̀ nípa MC Oluomo àti ìdí tí ọ̀pọ̀ ṣe gbàgbọ́ pé alágbára ni". BBC News Yorùbá. 12 March 2022. Retrieved 2 July 2022. 
  2. "Wetin we know about MC Oluomo plan to release 'Service to Humanity' book". BBC News Pidgin. https://www.bbc.com/pidgin/tori-55910593. 
  3. Abdullah, Abdulsalam (2024-11-11). "MC Oluomo sworn in as NURTW national president". TheCable. Retrieved 2024-11-15. 
  4. "MC Oluomo you didn’t know". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 13 March 2022. Retrieved 2 July 2022. 
  5. "Exaltation of an area boy: MC Oluomo and the rest of us". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 12 April 2022. Retrieved 2 July 2022. 
  6. "MC Oluomo is Coming For Us All – THISDAYLIVE". www.thisdaylive.com. Retrieved 2 July 2022.