Madam Koi Koi (tí a tún mọ̀ sí Lady Koi Koi, Miss Koi Koi, Madam High Heel tàbí Madam MokeGhana àti Miss Konkoko ni Tanzania ) jẹ́ òkú nínú àwọn ìtàn ìgbàanì ti ilẹ̀ Nàìjíríà àti Áfíríkà tó máa ń ṣẹ̀rùbà wọ́n ní ilé-ìgbé àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àti Ilé-ìgbọ̀nsẹ̀ ní àwọn ilé-ìwé lálẹ́. Africa.

[1][2]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "The legend of the dead teacher who haunts secondary school students". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-10-17. Retrieved 2021-09-29. 
  2. "Lady Koi-Koi & Other Crazy Secondary School Stories – StyleVitae" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-09-29.