Mae Jemison
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America
(Àtúnjúwe láti Mae C. Jemison)
Mae Carol Jemison [1] (ọjọ́ìbí 17 October, 1956) jẹ́ oníwòsàn àti arìnlófurufú fún NASA ará ilẹ̀ Amẹ́ríkà. Òhun ni obìnrin aláwòdúdú àkọ́kọ́ tó rinàjò lọ sí inú òfurufú nígbà tó rinàjò lọ pẹ̀lú Ọkọ̀-ayára Òfurufú Endeavour ní September 12, 1992.
Mae Jemison | |
---|---|
Arìnlófurufú NASA | |
Orílẹ̀-èdè | ará Amẹ́ríkà |
Ipò | Ti fẹ̀yìntì |
Ìbí | 17 Oṣù Kẹ̀wá 1956 Decatur, Alabama |
Iṣẹ́ míràn | Oníwòsàn Olùkọ́ |
Àkókò ní òfurufú | 190 h 30 min 23 s |
Ìṣàyàn | 1987 NASA Group |
Ìránlọṣe | STS-47 |
Àmìyẹ́sí ìránlọṣe |
- ↑ Who is Mae Jemison,Twinkl Teaching Wiki
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣeWikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Mae Jemison |