Maina Maaji Lawan

Olóṣèlú Nàìjíríà

Maina Maaji Lawan jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó jẹ́ Gómìnà Ìpínlẹ̀ Borno tẹ́lẹ̀. Wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú àríwá Ìpínlẹ̀ Borno ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà.[1][2] Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2011 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú All Nigeria Peoples Party ANPP.[3]

Maina Maaji Lawan
House of Representative for Kukawa NE
In office
Ọjọ́ kínín Oṣù kẹwá Ọdún 1979 – Ọjọ́ Ọkànlélọ́gbọ̀n Oṣù Kejìlá Ọdún 1983
Governor of Borno State
In office
Oṣù kínín Ọdún 1992 – Oṣù kọkànlá Ọdún 1993
AsíwájúMohammed Marwa
Arọ́pòIbrahim Dada
National Senator for Borno North
In office
Ọjọ́ Ọkàndínlọ́gbọ̀ Oṣù karún Ọdún 1999 – Ọjọ́ Ọkàndínlọ́gbọ̀ Oṣù karún Ọdún 2003
Arọ́pòMohammed Daggash
National Senator for Borno North
In office
Ọjọ́ Ọkàndínlọ́gbọ̀ Oṣù karún Ọdún 2007 – Ọjọ́ Ọkàndínlọ́gbọ̀ Oṣù karún Ọdún2011
National Senator for Borno North
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
Ọjọ́ Ọkàndínlọ́gbọ̀ Oṣù karún Ọdún 2011
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíỌjọ́ kejìlá Oṣù keje Ọdún 1954
Kauwa
Ọmọorílẹ̀-èdèỌmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Nigeria Peoples Party (ANPP)
Alma materAhmadu Bello University (ABU)
OccupationOníṣòwò
ProfessionOlóṣèlú
WebsiteOjú òpó wẹ́ẹ̀bù rẹ̀

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Sen. Maina Maaji Lawan". National Assembly of Nigeria. Archived from the original on 2008-12-22. Retrieved 2009-10-05. 
  2. "An Improved Senate, But Some Uninspiring Senators...". This Day. 24 May 2009. Retrieved 2009-10-05. 
  3. James Bwala (15 April 2011). "NASS election: Why Sheriff lost". Nigerian Tribune. Retrieved 2011-04-21.