Malawa

Oúnjẹ ilẹ̀ Somalia

Malawa jẹ́ pankéèkì tí ó dùn pancake tí ó ṣẹ̀ wá láti Somalia.[1] Ó jẹ́ ẹ̀yà pankéèkì tí wọ́n máa ń jẹ dáadáa ní Somalia, Djibouti, apá kan Ethiopia àti Kenya.

Àgbéyẹ̀wò

àtúnṣe

Malawah jẹ́ pankéèkì dídùn ìwọ̀n abọ́ tí wọ́n máa ń jẹ́ fún oúnjẹ àárọ̀ tàbí gẹ́gẹ́ bí ìpápánu ní ìgbàkúgbà ní ojú ọjọ́.[2] Ó jọ pankéèkì pẹlẹbẹ dídùn ó sì máa ń di fífi adùn kún pẹ̀lú cardamom.[3]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Mohamed Diriye Abdullahi, Culture and Customs of Somalis, (Greenwood Press: 2001), p. 113.
  2. "Malawah (Somali Sweet Pancakes) | The Somali Kitchen". www.somalikitchen.com. 
  3. Ahmed, Ifrah F. (17 January 2024). "Malawax (Cardamom Crepe) Recipe". NYT Cooking (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-01-28.