Malcolm Ohanwe (tí wọ́n bí ní ọdún 1993 ní Munich ) jẹ́ akọroyin, ará German-Nigerian, gbajúgbajà lórí ẹ̀rọ-ayélujára àti olóòtú ètò orí ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán. eniyan media ati agbalejo TV.

Malcolm Ohanwe
Ohanwe in 2009
Ọjọ́ìbíMalcolm Oscar Uzoma Ohanwe
Munich, Germany
Iléẹ̀kọ́ gígaLudwig Maximilian University of Munich
Iṣẹ́
  • Journalist
  • author
  • anchor
Ìgbà iṣẹ́2009–present

Ìgbésí ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Malcolm Ohanwe tí wọ́n bí ní Munich, ní Germany, ìyá rẹ̀ jẹ́ ará Palestine, nígbà tí bàbá rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ Naijiria.[1][2] Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi akọ̀ròyìn lẹ́yìn tó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní ilé-ìwé girama, gẹ́gẹ́ bí òǹkọ̀wé fún German television network ProSieben, àti bíi olóòtú ilé-iṣẹ́ German kan, tí orúkọ wọn lórí ẹ̀rọ-ayélujára ń jẹ́ Rap2Soul.de.[3]Ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa èdẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì, Middle Eastern Studies, àti Romance Studies ní Ludwig-Maximilians-University, ní Munich. Lẹ́yìn náà, ó kọ́ èdè Arabic, German, English, French, Italian Àti Spanish, ó sì ń fi ṣe iṣẹ́.[4]

Àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀

àtúnṣe
  • 2019: International Music Journalism Award. For his Wir sind zu viele: Warum deutscher Pop nicht mehr weiß bleibt (Best Work of Music Journalism, Under 30)[5]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe