Malin Maria Åkerman[lower-alpha 2] (tí a bí ní ọjọ́ kejìlá oṣù karùn-ún ọdún 1978) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀ èdè Sweden. Ní àárín ọdún 2003 sí 2004, ó farahàn nínú eré The Utopian Society (2003) àti Harold & Kumar Go to White Castle (2004). Lẹ́yìn ìgbà tí ó farahàn nínú eré HBO tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ The Comeback (2005), ó farahàn nínú àwọn eré bi The Heartbreak Kid (2007), 27 Dresses (2008), The Invasion (2007). Ó kó ipa Silk Spectre II nínú eré Watchmen (2009), èyí sì mú kí wọ́n yàn án mọ́ ara àwọn tí ó tó sí àmì ẹyẹ Saturn Award

Malin Åkerman
Akerman, 2024
Ọjọ́ìbí12 Oṣù Kàrún 1978 (1978-05-12) (ọmọ ọdún 46)
Stockholm, Sweden
Ọmọ orílẹ̀-èdè
Iṣẹ́
  • Actress
  • model
Ìgbà iṣẹ́1997–present
Olólùfẹ́
Àwọn ọmọ1

Ní ọdún 2009, Åkerman ṣeré nínú The Proposal àti Couples Retreat. Láàrin ọdún 2010 sí 2016, ó ṣeré nínú eré àwàdà Adult Swim tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Childrens Hospital. Àwọn eré míràn tí ó ti farahàn ni Wanderlust, Rock of Ages, Trophy Wife (2013–2014), I'll See You in My Dreams (2015), Rampage (2018) àti nínú Billions gẹ́gẹ́ bi Lara Axelrod.

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Swedish Actress Malin Åkerman Becomes a US Citizen". swedesinthestates.com. 25 October 2018. Archived from the original on 25 May 2021. Retrieved May 25, 2021.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. Àdàkọ:Cite AV media


Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref> tags exist for a group named "lower-alpha", but no corresponding <references group="lower-alpha"/> tag was found