Mamarumo marokane
Mamarumo Marokane (bí ní. 1997) jẹ́ Òṣèré àti Òlùṣètò South African. Wọ́n mọ̀ ọ́ fún ìfarahàn rẹ̀ ní Shadow and MTV Shuga.
Mamarumo Marokane | |
---|---|
Marokane in 2019 | |
Ọjọ́ìbí | c. 1996[1] |
Orílẹ̀-èdè | South African |
Ẹ̀kọ́ | CityVarsity School of Media and Creative Arts |
Iṣẹ́ |
|
Height | Àdàkọ:Infobox person/height |
Ìbẹ̀rẹ̀ Ayé rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Marokane ní ọdún 1996 láìmọ̀ àsìkò gan-an.[1] Ó kàwé ní CityVarsity School of Media and Creative Arts. Ó lè sọ èdè Gẹ̀ẹ́sì, èdè Sepedi àti èdè Setswana.[2]
Iṣé-Ààyò
àtúnṣeLọ́wọ́ ó ṣe Vuvu lórí àbùkù pẹ̀lú àwọn ọmọ méjì kan látara ọ̀rẹ́kùnrin tó fẹ́ sẹ́yìn tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ Nhlamulo. Marokane gba òkìkí látara àfihàn rẹ̀ nínu eré-ẹlẹ́sẹsẹ Shadow[3] àti lórí MTV Shuga níbi tí ó ti ṣe Dineo.[4]
Ní oṣù kejì ọdún 2020, Marokane gba ipò tàbí orúkọ gẹ́gẹ́ bí àwọn Òṣèré mẹ́rin tí ó ṣìṣè dìde la tọwọ́ Pearl Thusi ní Cosmopolitan South Africa.[1] Ó dára pọ̀ mọ́ àwọn Òṣèré ọlọ́wọ̀ bí nòm̀bà díẹ̀ fún eré lálẹ́ ẹlẹ́sẹsẹ tí wọ́n pè ní MTV Shuga Alone Together tí ó ṣe àwọn àfihàn ìṣòro Coronavirus ní ọjọ́ ogún oṣù kẹ́rin, ọdún 2020.[5][6]
References
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 1.2 Mafu, Noxolo (2020-02-23). "Meet the four rising stars Pearl Thusi has dubbed as the next big things". Cosmopolitan SA (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-04-29.
- ↑ 2.0 2.1 "Mamarumo Marokane" (PDF). Canvas CAM. Archived from the original (PDF) on 19 August 2019. Retrieved 30 April 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Biography ofMamarumo Marokanefor Appearances, Speaking Engagements". www.allamericanspeakers.com. Retrieved 2020-04-29.
- ↑ "MTV Shuga: Down South (S2) Mamarumo Marokane talks about her character Dineo". YouTube MTV Shuga. 3 May 2019. Retrieved 29 April 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Every Woman Every Child partners with the MTV Staying Alive Foundation to Tackle COVID-19". Every Woman Every Child (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-04-16. Archived from the original on 2021-10-09. Retrieved 2020-04-30.
- ↑ Akabogu, Njideka (2020-04-16). "MTV Shuga and ViacomCBS Africa Respond to COVID-19 with "Alone Together" Online Series". BHM (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-04-30.