Mambila

eya orile-ede Naijiria ati ti Cameroon

Mambila Àwọn ènìyàn yìí wà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ati Kamẹrúùnù, wọ́n tó ẹgbẹ̀rún lọ́na mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n, wọ́n sì múlé ti àwọn ènìyàn bíi kaka, Tikong àti Bafum. Èdè Mambila, ẹ̀yà Bantu ni wọ́n sì ń sọ. Àgbẹ, ọde,̣ apẹja àti ọ̀ṣìn ẹran ni ìṣe wọn. Ẹ̀sìn Mùsùlùmí àti ti ìbílẹ̀ ni wọ́n ń ṣe papọ̀. Àwọn wọnyi wa ni Orílẹ́ èdè Nàìjíríà àti Kamẹrúùnù. wọn jẹ ẹya Bantu. Àwọn kaka, Tikong ati Bafun ni wọn jọ pààlà. Ẹsin ibilẹ ati ẹsin musulumi ni wọn n sin.