Manaka Ranaka
Manaka Ranaka (bíi ni ọjọ́ kẹfà oṣù kẹrin ọdún 1979)[2] jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà tí ó gbajúmọ̀ fún ipá tí ó kó nínú eré Generations: The Legacy. Ó kó ipa Nandipha Sithole nínú eré Isindigo. Ní ọdún 2007, ó gbà ẹ̀bùn òṣèré tó dára jù lọ nínú ẹ̀fẹ̀ láti ọ̀dọ̀ South African Film and Television Award.[3] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Dinwiddie high school. Ó bí ọmọ méjì tí orúkọ wọn jẹ́ Katlego àti Naledi.[4]
Manaka Ranaka | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 6 Oṣù Kẹrin 1979 Soweto,Johannesburg ,South Africa |
Ẹ̀kọ́ | Dinwiddie high school |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1999–present |
Net worth | $ 1 million[1] |
Àwọn ọmọ | 2 |
Parent(s) | Kgotlaesele Ranaka (father) Nonceba Ranaka (mother) |
Àwọn olùbátan | Dineo Ranaka (sister) Mpumi Ranaka (sister) Ranaka Ranaka (brother) Mzingisi "Ziggy" Ranaka (brother) Michelle Ranaka (sister-in-law) |
Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀
àtúnṣeỌdún | Àkọ́lé | Ipa tí ó kó |
---|---|---|
2000 | Isidingo | Nandipha Sithole |
2002 | Gaz’lam | Portia |
2006 | One Way | Nozuko |
2007 | Home affairs | Neli |
2007 | dubbed Society | Ayanda |
2012 | Rhythm City | Zanele Kgaditse |
2014-Present | Generations:The Legacy | Lucy Diale |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Albert Simiyu (16 August 2019). "Manaka Ranaka Biography:Age,husband,daughter,siblings,Generations,car accident Instagram and net worth". briefly.co.za.
- ↑ "Archived copy". Archived from the original on 2015-07-13. Retrieved 2015-06-14. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Manaka Ranaka Bio, Wiki, Age, Husband, Daughters, Sisters, Siblings, Family, Career Highlights, Net Worth". globintel.com. 7 October 2018. Archived from the original on 2020-11-09. Retrieved 2020-10-28.
- ↑ "10 Things You Didn’t Know About Manaka Ranaka". youthvillage.co.za. Archived from the original on 2020-07-03. Retrieved 2020-10-28.