Mandraka Dam jẹ́ ìdídò lórí odò Mandraka ní tòsí Mandraka ní Ẹkun Analamanga tí Madagascar. Ilé-iṣẹ Faranse ní o kọ ìdídò náà ní ọdún 1956 ó si ṣẹda Lake Mandraka.[1]

Mandraka Power Station

àtúnṣe

Ìdídò náà pèsè omi si 24 megawatts (32,000 hp) ibùdó agbára hydroelectric 1.9 kilometres (1.2 mi) si ìlà-oòrùn, Ní ìsàlẹ̀ àfonífojì. Ìyípadà láàrin ìdídò àti ibùdó agbára n fúnni ni ori hydraulic lórí 226 metres (741 ft).[2][3] Jirama ní o ṣiṣẹ àti ni o ní ìdíbò àti ibùdó àti àwọn mẹ́rin mẹ́fà 6 megawatts (8,000 hp) Pelton tobaini -generators wọn fífún láàrín 1958 ati 1972.[4]

Wó eléyìí na

àtúnṣe
  • Mantasoa Dam - ní gbá kún gba ni omi máa n sọ si Mandraka Dam

Àwọn itọkasi

àtúnṣe
  1. "The French civil engineering works in the world dams 1860-2012" (PDF). IESF. Archived from the original (PDF) on 18 March 2014. Retrieved 17 March 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Dams of Madagascar". UN FAO. Archived from the original on September 5, 2013. Retrieved 17 March 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "References – ANDRITZ HYDRO". Andritz. Archived from the original on 18 March 2014. Retrieved 18 March 2014. 
  4. "Hydroelectric Power Plants in Southern Africa". IndustCards. Archived from the original on 19 July 2009. Retrieved 18 March 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)