Manuel Dorrego (11 June 1787 – 13 December 1828) je ara orile-ede Argentina ati ọmọ-ólógun. Ó jẹ́ Gómìnà Buenos Aires ní ọdún 1820, tí wón sì yan sipo lekansi laarin ọdún 1827 si 1828.

Manuel Dorrego
Interim Gómìnà Buenos Aires Province
In office
29 June 1820 – 20 September 1820
AsíwájúMiguel Estanislao Soler
Arọ́pòMartín Rodríguez
Gómìnà Buenos Aires Province
In office
13 August 1827 – 1 December 1828
AsíwájúJuan Gregorio de Las Heras
Arọ́pòJuan Lavalle
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí11 June 1787
Buenos Aires, Viceroyalty of the Río de la Plata, Spanish Empire
Aláìsí12 December 1828(1828-12-12) (ọmọ ọdún 41)
Navarro, United Provinces of the Río de la Plata
Resting placeLa Recoleta Cemetery
Ọmọorílẹ̀-èdèArgentina
Ẹgbẹ́ olóṣèlúFederal
Alma materReal Universidad de San Felipe
ProfessionMilitary
Military service
AllegianceUnited Provinces of the Río de la Plata
UnitArmy of the North
Battles/warsSecond Upper Peru campaign

Ìgbésíayé àti òṣèlú

àtúnṣe

Dorrego ni wón bí si Buenos Aires ni ọjọ kọkànlá oṣù kẹfà ọdún 1787 sí ìdílé José Antonio do Rego, ati María de la Ascensión Salas. Ó bẹ̀rẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ Real Colegio de San Carlos ní ọdún 1803, ti o si kuro lọ síReal Universidad de San Felipe ni Captaincy General of Chile lati keko rẹ lọ.[1]

O kó kúrò lọ sí United Provinces of the Río de la Plata (tí wón pe ni Argentina lóde òní), ti o si dárapọ̀ mọn Army of the North, lábẹ asẹ Manuel Belgrano. Ó jà níbi awọn ogun Tucumán ati Salta, tí ò sìse loju ogun mejeji.[1]

  1. 1.0 1.1 Galasso, p. 257