Maputaland jẹ́ àgbègbè kan ní Apágúúsù Áfríkà. Ó wà ní apá àríwá KwaZulu-Natal, South Africa láàrin Eswatini àti etí odò.[1] Àwọn míràn tún gbàgbọ́ pé apá kan gúúsù Mozambique wà lára rẹ̀. Àwọn ibi tí ẹyẹ ń gbà kọjá àti àwọn ẹranko tí à ń pè ní coral reefs tí ó wà nínú odò jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìdí tí ọ̀pọ̀lopọ̀ ma ń fí wá sí Maputaland.

Maputaland
Natural region
Irúgbìn kan ní Maputaland
Irúgbìn kan ní Maputaland
Maputaland is located in South Africa
Maputaland
Maputaland
Ibi tí Maputaland wà
Coordinates: 26°59′S 32°30′E / 26.983°S 32.500°E / -26.983; 32.500Coordinates: 26°59′S 32°30′E / 26.983°S 32.500°E / -26.983; 32.500
CountrySouth Africa

Ilẹ̀ Maputaland àtúnṣe

Àwọn Òkè Ubombo ni ó yí gúúsù Maputaland ká ní apá ìwọ̀ oòrùn, Òkun Índíà sì ló yíká ní apá ìlà oòrùn. Ilẹ̀ ibè tó 10,000 km2, láti ìlú Hluhluwe àti àríwá Lake St. Lucia títí dé àlà Mozambique àti South Africa, àti Maputo ní orílẹ̀ èdè Mozambique.[2]

Tongaland àtúnṣe

Wọ́n sọ apá ibìkan Maputaland ní Tongaland nítorí àwọn ènìyàn Tonga tí ó gbé níbẹ̀. Ṣùgbọ́n ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹfà ọdún 1895, Great Britain fi ipá gba Tongaland.

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. A survey of tropical southeastern Africa in the context of coastal zone management
  2. Contributions to the ecology of Maputaland, Southern Africa