Marcia Gay Harden
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America
Marcia Gay Harden ni wọ́n bí ní ọjọ́ kerìnlá, oṣù kẹjo ọdún 1959 jẹ́ òṣèrébinrin Orílẹ̀ èdè America tó ti gba orisirisi ebún bi Ebun Akademi, ati Tony Award.[1]
Marcia Gay Harden | |
---|---|
Harden in 2013 | |
Ọjọ́ìbí | 14 Oṣù Kẹjọ 1959 La Jolla, California, U.S. |
Ẹ̀kọ́ | University of Texas, Austin (BA) New York University (MFA) |
Iṣẹ́ | Òṣérébinrin |
Ìgbà iṣẹ́ | 1979–present |
Olólùfẹ́ | Thaddaeus Scheel (m. 1996; div. 2012) |
Àwọn ọmọ | 3 |
Awards | Full list |
Ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́
àtúnṣeWọ́n bí sí La Jolla, California, omo-bíbi Beverly Harden (née Bushfield).[2] Harden parí ní ile eko girama ti Surrattsville, Clinton, Maryland ni odun 1976.O parí ni Yunifasiti Texas to wa ni olúlú Austin ni odun 1980. O keko gboye Masters of Fine Arts lati fásitì New York University's Tisch School of Arts ni odun 1988.[3]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Marcia Gay Harden". Dallas Museum of Art. March 15, 2018. Retrieved August 29, 2022.
- ↑ "- Turner Classic Movies". Turner Classic Movies. August 21, 2022. Retrieved August 29, 2022.
- ↑ https://www.backstage.com/magazine/article/character-studies-marcia-gay-harden-19705/
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |