Marisa Tomei
Marisa Tomei ( /toʊˈmeɪ/; tí a bí ní oṣù kejìlá ọjọ́ kẹrin, ọdún 1964)[1] jẹ́ òṣèré obìnrin Ilẹ̀ Amẹ́ríkà. Ó jẹ́ olùgbà orísirísi iyì, lára rẹ̀ ni àmì ẹ̀yẹ Akádẹ́mì, ní àfikún sí àwọn yíyàn tó gbà fún British Academy Film Award, Daytime Emmy Award kan, Golden Globe Award méjì, àti Screen Actors Guild Award mẹ́ta.
Marisa Tomei | |
---|---|
Tomei at the 2018 Tribeca Film Festival | |
Ọjọ́ìbí | 4 Oṣù Kejìlá 1964 Brooklyn, New York, U.S. |
Ẹ̀kọ́ | Boston University |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 1983–present |
Works | Full list |
Alábàálòpọ̀ | Logan Marshall-Green (2008–2012) |
Awards | Full list |
Lẹ́hìn iṣẹ́ rẹ̀ lórí àwọn jara tẹlifísàn "As the World Turns" (ọdún 1983 sí 1985), Tomei wá sí iyì nípasẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ lórí"The Cosby Show" spin-off "A Different World " ní ọdún 1987. Lẹ́hìn tí ó ṣe àwọn iṣẹ́ kékèké nínú fíìmù kọ̀ọ̀kan, ó wá sí ìdánimọ̀ àgbáyé ní ọdún 1992 pẹ̀lú eré apanilẹ́rìn-ín "My Cousin Vinny", tí ó fi gba ẹ̀bùn àmì ẹ̀yẹ fún òṣèré àtìlẹ́yìn obìnrin tó dára jùlọ. She received two additional Academy Award nominations for In the Bedroom (2001) and The Wrestler (2008).
Tomei has appeared in a number of successful films, including What Women Want (2000), Anger Management (2003), Wild Hogs (2007), The Ides of March (2011), and Parental Guidance (2012). She also portrayed May Parker in the Marvel Cinematic Universe, having appeared in Captain America: Civil War (2016), Spider-Man: Homecoming (2017), Avengers: Endgame (2019), Spider-Man: Far From Home (2019), and Spider-Man: No Way Home (2021).
Tomei was formerly involved with the Naked Angels Theater Company and appeared in plays, such as Daughters (1986), Wait Until Dark (1998), Top Girls (2008), for which she received a nomination for the Drama Desk Award for Outstanding Featured Actress in a Play, and The Realistic Joneses (2014), for which she received a special award at the Drama Desk Awards.
Àwọn Ìtọ́ka Sí
àtúnṣe- ↑ "Marisa Tomei Biography". Biography.com. Archived from the original on October 6, 2014. Retrieved October 5, 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)