Marseille
- Marseille wa ni ipoidojuko 43°17′47″N 5°22′12″E / 43.296346°N 5.369889°ECoordinates: 43°17′47″N 5°22′12″E / 43.296346°N 5.369889°E
Marseille (ìpè Faransé: [maʁ.ˈsεj]) jẹ́ ìlú èbúté ìgbàanì, èyí tá a dá nǹkan bíi 600 ṣááju Sànmánì Tiwa, ní apá gúúsù-ìlàoòrùn Fránsì. Agbègbè náà tóbi tó 240.62 km², tí àwọn ènìyàn inú rẹ̀ sí jẹ́ 858,120 nígbà ìkànìyàn ọdún 2013.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- Ojú-òpó wẹ́ẹ̀bù Archived 2016-02-21 at the Wayback Machine. (Faransé) (Gẹ̀ẹ́sì) (Híspánì)
- Ìrìn-àjò Afẹ́ (Faransé) (Gẹ̀ẹ́sì) (Jẹ́mánì) (Híspánì) (Chinese)