Martin Luther King, Jr.

Olóṣèlú

Martin Luther King, Jr.(January 15, 1929April 4, 1968) jẹ́ ẹni ọ̀wọ̀, alákitiyan ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà,[1] bẹ́ẹ̀ ni ó sí jẹ́ olórí ẹgbẹ́-ìjíndé fún ẹ̀tọ́ ọmọ-àwùjọ ni ilé Amẹ́ríkà. Gẹ́gẹ́ bí oníwasú Ìjọ Onítẹ̀bọmi, King di alakitiyan fún ẹ́tọ́ ará-ìlú ní ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀.

Dr. Martin Luther King, Jr.

Ọjọ́ ìbí: (1929-01-15)Oṣù Kínní 15, 1929
Place of birth: Atlanta, Georgia, USA
Ọjọ́ aláìsí: April 4, 1968(1968-04-04) (ọmọ ọdún 39)
Place of death: Memphis, Tennessee, USA
Movement: African-American Civil Rights Movement and Peace Movement
Major organizations: Southern Christian Leadership Conference
Notable prizes: Nobel Peace Prize (1964)
Presidential Medal of Freedom (1977, posthumous)
Congressional Gold Medal (2004, posthumous)
Major monuments: Martin Luther King, Jr. National Memorial (planned)
Religion: Baptist
Influences Howard Thurman, Mahatma Gandhi, Henry David Thoreau, Bayard Rustin, Jesus Christ
Influenced Coretta Scott King, Jesse Jackson

Ìgbà èwe rẹ̀

àtúnṣe

Àwọn Ìtọ́ka sí

àtúnṣe
  1. "The Nobel Peace Prize 1964". NobelPrize.org. 1929-01-15. Retrieved 2020-04-04.