Martina Ohadugha

Agbaọ́ọ̀lù ọmọ orílé-éde Nàìjíríà

Martina Ohadugha jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 5, óṣu May ni ọdun 1991. Arabinrin naa ṣere gẹgẹbi midfielder fun River Angels[1][2][3].

Martina Ohadugha
Personal information
OrúkọOnyinyechi Martina Ohadugha
Ọjọ́ ìbí5 Oṣù Kàrún 1991 (1991-05-05) (ọmọ ọdún 33)
Ibi ọjọ́ibíNigeria
Ìga1.62m
Playing positionMidfielder
Club information
Current clubRivers Angels
Number19
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
Rivers Angels
National team
2012–Nigeria women's national football team35(2)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 18:34, 17 June 2015 (UTC)

Àṣeyọri

àtúnṣe
  • Martina kopa ninu ere idije awọn obinrin ilẹ afirica ni ọdun 2012 ati 2014. Arabinrin naa kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agbaye ni ọdun 2015[4].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://www.eurosport.com/football/martina-ohadugha_prs425363/person.shtml
  2. https://fbref.com/en/players/f1046914/Martina-Ohadugha
  3. https://ng.soccerway.com/players/martina-ohadugha/135285/
  4. https://africanfootball.com/news/617324/27-players-hit-Super-Falcons-camp