Marty Allen
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America
Morton David Alpern (March 23, 1922 – February 12, 2018), tí ọ̀pọ̀ ènìyàn mọl sí Marty Allen, jẹ́ apanilẹ́rìn-ín, òṣèrékùnrin à ti onínúure ti Orílẹ̀ èdè America. Ó ṣeré gẹ́gẹ́ bí i apanilẹ́rìn-ín ní ilé-ijó, tí wọ́n sì máa ń pè é ní "The Darling of Daytime TV".[1][2]
Marty Allen | |
---|---|
Allen in 1960 | |
Orúkọ àbísọ | Morton David Alpern |
Ìbí | Pittsburgh, Pennsylvania, U.S. | Oṣù Kẹta 23, 1922
Aláìsí | February 12, 2018 Las Vegas, Nevada, U.S. | (ọmọ ọdún 95)
Medium | Stand-up, television, film acting |
Ajẹ́ọmọorílẹ̀-èdè | American |
Years active | 1950–2018 |
Spouse | Lorraine "Frenchy" Trydelle (m. 1960; died 1976) Karon Kate Blackwell (m. 1984) |
Ibiìtakùn | Official website (archived August 22, 2009) |