Marwa Zein jẹ́ olùdarí eré, ònkọ̀tàn, àti olùgbéréjáde lórílẹ̀-èdè Sudan. Òun ni ó kọ ìwé-ìtàn ti ọdún 2019 kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Khartoum Offside. Ó maá n lo àwọn iṣẹ́ rẹ̀ láti fi ṣe àgbàwí àti láti fi jà fún ẹ̀tọ́ àwọn obìnrin.[1][2] Òun ni olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ agbéré-jáde tí wọ́n pè ní ORE Production, èyí tí ó wà ní ìlú Khartoum. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn méjẹ tí ẹgbẹ́ International Emerging Film Talent Association (IEFTA) yàn kááríayé láti wà níbi ayẹyẹ Cannes Film Festival 2019 gẹ́gẹ́ bi àwọn àlejò pàtàkì.[3]

Marwa Zein
Ọjọ́ìbíMarwa Zein
Orílẹ̀-èdèSudanese
Iṣẹ́
Gbajúmọ̀ fún

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "New York African Film Festival Goes Virtual with Streaming Rivers: The Past into the Present". Film at Lincoln Center. November 19, 2020. Retrieved November 20, 2020. 
  2. Diffrient, David Scott. "Sudan Offside". acts.Human Rights Film Festival. Retrieved November 20, 2020. 
  3. "7 FILMMAKERS SELECTED FOR CANNES 2019". IEFTA. Retrieved November 20, 2020. 

Àwọn ìtakùn Ìjásóde

àtúnṣe