Mary Berko
Mary Berko jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ akọkọ, óṣu june ni ọdun 1988. Agbabọọlu naa ṣere fun Police Accra gẹgẹbi midfielder[1].
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 1 Oṣù Kẹfà 1988 | ||
Playing position | Midfielder | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Police Accra | |||
National team‡ | |||
Ghana women's national football team | |||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Àṣeyọri
àtúnṣe- Mary kopa ninu ere idije awọn obinrin ilẹ afirica to waye ni ọdun 2014[2].