Mary Essiful
Mary Essiful jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ 22, óṣu June ni ọdun 1993. Agbabọọlu naa ṣere fun Rivers Angels F.C. gẹgẹbi midfielder[1].
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 22 Oṣù Kẹfà 1993 | ||
Playing position | Midfielder | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Soccer Intellectuals Ladies | |||
National team‡ | |||
Ghana women's national football team | |||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Àṣeyọri
àtúnṣe- Mary kopa ninu ere idije awọn obinrin ilẹ afirica ti ọdun 2014[2].