Mary McLeod Bethune

Olóṣèlú

Mary Jane McLeod Bethune (July 10, 1875 – May 18, 1955) je oluko ati alakitiyan eto araalu ara Amerika to gbajumo fun didasile ile-eko fun awon omo Afrika Amerika ni Daytona Beach, Florida, to pada di Bethune-Cookman University ati fun jije oludamoran si Aare Franklin D. Roosevelt.

Mary Jane McLeod Bethune
Mary Jane McLeod Bethune, je yiya ni foto latowo Carl Van Vechten, April 6, 1949
Ọjọ́ìbí(1875-07-10)Oṣù Keje 10, 1875
Mayesville, South Carolina, United States
AláìsíMay 18, 1955(1955-05-18) (ọmọ ọdún 79)
Daytona Beach, Florida, United States
Iṣẹ́Oluko, Oluda, Olori Isakitiyan Eto Araalu awon omo Afrika Amerika
Olólùfẹ́Albertus Bethune, alaisi ni 1918Itokasi àtúnṣe