Mary Soronadi
Mary Soronadi (tí wọ́n bí ní ọjọ́ karùndínlógún oṣù kẹjọ ọdún 1971) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó máa ń kópa nínú ìdíje bọ́ọ̀lù aláfọwọ́gbá.[1] Ó kópa nínú ìdíje àwọn obìnrin ní 1992 Summer Olympics.[2][3]
Òrọ̀ ẹni | |
---|---|
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọjọ́ìbí | 15 Oṣù Kẹjọ 1971 |
Sport | |
Erẹ́ìdárayá | Handball |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Olympedia – Nigeria in Handball". Olympedia – Main Page. Retrieved 2024-04-25.
- ↑ "Mary SORONADI". Olympics.com. 2023-06-12. Retrieved 2024-04-25.
- ↑ "Nigerian female handball players". FamousFix.com. 1973-11-11. Retrieved 2024-04-25.