Mary Twala
Mary Kuksie Twala (bíi ni ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹsàn-án ọdún 1939)[2] jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà. Ní ọdún 2011, wan yàn kalẹ̀ fún ẹ̀bùn Best Actress in a Supporting Role lati ọdọ Africa Movie Academy Award .
Mary Twala-Mhlongo | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Mary Kuksie Twala 14 Oṣù Kẹ̀sán 1939 Soweto, Johannesburg, Union of South Africa |
Aláìsí | 4 July 2020[1] Parklane Private Hospital, Johannesburg, South Africa | (ọmọ ọdún 80)
Orílẹ̀-èdè | South African |
Orúkọ míràn | Mampinga |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 1960s – 2020 |
Notable work | Hlala Kwabafileyo, Molo Fish, Ubizo: The Calling, Yizo-Yizo |
Olólùfẹ́ | Ndaba Mhlongo (deceased) |
Ẹbí |
|
Iṣẹ́
àtúnṣeTwala tí kópa nínú orísìírísìí eré ìbílẹ̀ ni South Áfríkà. Ó kópa nínú eré Hopeville gẹ́gẹ́ bíi Ma Dolly, èyí sì jẹ kí wọn pé fún ẹ̀bùn Best Supporting Actress láti ọ̀dọ̀ Africa Movie Academy Awards.
Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀
Ikú
àtúnṣeMary Twala kú ní ọjọ́ kẹrin oṣù keje, ọdún 2020 ni ago mọ́kànlá ni ilẹ̀ ìwòsàn àdáni tí Parklane private hospital ni ìlú Johannesburg.[9] Wọ́n sín ni ọjọ́ kẹsàn-án oṣù keje, ọdún 2020 ni ìlú Soweto.
Awọn Itọkasi
àtúnṣe- ↑ Nyathi, Ayanda. "Legendary SA actress Mary Twala dies at 80". ewn.co.za. Archived from the original on 2020-07-07. Retrieved 2020-10-12.
- ↑ "Ms Mary Twala Mhlongo". thepresidency. Archived from the original on 10 December 2019. Retrieved 15 April 2020.
- ↑ Stead, Andy. "Global acclaim for Hopeville". gautengfilm.org.za. Archived from the original on 15 September 2018. Retrieved 4 July 2020.
- ↑ "Mary Twala profile". tvsa.co.za. Retrieved 4 July 2020.
- ↑ Izuzu. "Fabian Adeoye Lojede, Bimbo Akintola, Hakeem Kae Kazim star in new movie". Pulse. Retrieved 4 July 2020.
- ↑ Kyle, Zeeman. "Mary Twala to make her big screen return". channel24.co.za. Retrieved 4 July 2020.
- ↑ Avantika, Seeth. "Suspense, drama and comedy jam-packed into an amazing local production". channel24.co.za. Retrieved 4 July 2020.
- ↑ "Local movie premiere draws hundreds". Channel 24. Retrieved 4 July 2020.
- ↑ "BREAKING: Veteran actress Mary Twala passes away". MzansiNewsLive (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-07-04. Retrieved 2020-07-04.