Mary Uduma
Mary Uduma (bíi ni ọjọ́ meedogbon oṣù karùn-ún ọdún 1952)[1] jẹ́ olùdarí ni ẹ méjì fún Nigeria Internet Registration Association (NIRA).[2][3] Òun ni alága fún Nigeria Internet Governance Forum.[4][5]
Mary Uduma | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | May 25, 1952 |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Organization | Nigeria Internet Registration Association |
Ẹ̀kọ́
àtúnṣeUdoma gboyè nínú ẹ̀kọ́ Accounting lati ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Institute of Management Technology àti University of Lagos.[1]
Iṣẹ́
àtúnṣeUduma sì ṣé pelu Federal Audit ni ìgbà tí ó wà ní ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Lagos. Ó padà wá si ṣé pelu Ivory Merchant Bank. Ní ọdún 1995, ó darapọ̀ mọ́ Nigerian Communications Commission gẹ́gẹ́ ìgbà kejì adarí owó. Ní ọdún 1999, ó di ìgbà kejì adarí ni ẹ̀kà tí Tariff and Charges. Wọn gbé lọ sí Corporate planning ni ọdún 2005, ó sì ṣíṣe nibe fún ọdún kan kí ó tó di adarí fún Licensing. Ó di olórí fún ẹ̀ka Consumers affairs ni odun 2011.[1] Uduma tí ṣe ìgbà kejì olùdarí fún Nigeria Internet Registration Association kí ó tó wà di olùdarí kejì fun ẹgbẹ́ náà. Ó ṣe olùdarí ni ẹ méjì fún ẹgbẹ́ náà.[6] Òun ni alága fún Nigeria Internet Governance Forum.[7][8] Ó ṣe aṣojú fún NIGF ni ọdún 2019 ni ayẹyẹ ọjọ́ tí wọn yà kalẹ fún àwọn obìnrin ni gbogbo agbaye tí wọn ṣe ni Abuja.[9]
Ẹ̀bùn
àtúnṣeNí ọdún 2016, ó gbà ẹ̀bùn láti ọdọ NIRA Presidential Award.[10][11]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 1.2 "The Communicator Online - The Communicator Online". www.ncc.gov.ng. Retrieved 2020-05-08.
- ↑ "NiRA BOD - Nigeria internet Registration Association (NiRA)". www.nira.org.ng. Archived from the original on 2020-08-05. Retrieved 2020-05-08.
- ↑ "There is money in domain name business, NIRA Boss". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2010-09-07. Retrieved 2020-05-08.
- ↑ "#InternationalWomensDay: Working on digital inclusion for women —NIGF". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-03-08. Retrieved 2020-05-08.
- ↑ "Nigeria's internet users reaches 103m - NCC - P.M. News". www.pmnewsnigeria.com. Retrieved 2020-05-08.
- ↑ "NiRA Decries Govts, MDAs Hosting .ng Servers Abroad". Daily Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-03-16. Retrieved 2020-05-08.
- ↑ "ICT expert urges government to build more ICT hubs". Archived from the original on 2023-09-28. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "NIGF to focus on enabling digital commonwealth for growth". Archived from the original on 2023-09-28. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "IGF seeks women participation in internet governance for development". Archived from the original on 2023-09-28. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Mary Uduma, CFA, Wunmi Hassan Receive NiRA Presidential Awards 2016". CFAmedia.ng - Startups | Media | Business | Technology News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-04-04. Retrieved 2020-05-08.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Mary Uduma, others awarded at 2016 NiRA awards ceremony". TechCity (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-04-04. Retrieved 2020-05-08.