Matsuo Bashō
Àdàkọ:Contains Japanese text Matsuo Bashō (松尾 芭蕉 , 1644 – November 28, 1694), abiso Matsuo Kinsaku (松尾 金作 ), nigbana bi Matsuo Chūemon Munafusa (松尾 忠右衛門 宗房 )[1][2], je akoewi togbajumojulo ni igba Edo ni Japan. Nigba aye re, Bashō gbajumo fun awon ise re ninu iru collaborative haikai no renga alajobarasepo; loni, leyin opo orundun awiso lori ise re, o gbajumo bi oga ninu haiku soki ati kedere. Awon ewi re gbajumo kakiri aye.
- Láàrin orúkọ ará Japan yìí, orúkọ ìdílé ni Matsuo.
Matsuo Bashō (松尾 芭蕉) | |
---|---|
Pen name | Sōbō (宗房) Tōsē (桃青) Bashō (芭蕉) |
Iṣẹ́ | Poet |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Japanese |
Notable works | Oku no Hosomichi |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "松尾芭蕉". The Asahi Shimbun Company. Retrieved 2010-11-22.Àdàkọ:Ja icon
- ↑ "芭蕉と伊賀上野". 芭蕉と伊賀 Igaueno Cable Television. Retrieved 2010-11-22.Àdàkọ:Ja icon