Matti Vanhanen
Matti Taneli Vanhanen ( pronunciation (ìrànwọ́·ìkéde)) (ojoibi November 4, 1955) ni Alakoso Agba ile Finland lati 2003 titi di 2010, ati alaga egbe oloselu Keskusta(Centre Party of Finland) tele. Ni apa keji odun 2006 o je Aare Igbimopo Europe. Teletele o je oniroyin.
Matti Vanhanen | |
---|---|
Prime Minister of Finland | |
In office 24 June 2003 – 22 June 2010 | |
Ààrẹ | Tarja Halonen |
Deputy | Antti Kalliomäki Eero Heinäluoma Jyrki Katainen |
Asíwájú | Anneli Jäätteenmäki |
Arọ́pò | Mari Kiviniemi |
Minister of Defence | |
In office 17 April 2003 – 24 June 2003 | |
Alákóso Àgbà | Anneli Jäätteenmäki |
Asíwájú | Jan-Erik Enestam |
Arọ́pò | Seppo Kääriäinen |
Member of the Finnish Parliament for Uusimaa | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 22 March 1991 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 4 Oṣù Kọkànlá 1955 Jyväskylä, Finland |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Centre Party |
Alma mater | University of Helsinki |
Profession | Political science Social science Journalist |
Signature |
Ise
àtúnṣeVanhanen je bibi ni Jyväskylä, omo ojogbon Tatu Vanhanen, to je ekeji-olukowe IQ and the Wealth of Nations, ati Anni Tiihonen.
O ko eko sayensi oloselu ni Yunifasiti ilu Helsinki, o si pari pelu iwe-eri Master ninu Sayensi Awujo ni 1989 [1].
Itokasi
àtúnṣe
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |