Maureen Mmadu
Maureen Nkeiruka Mmadu (wọ́n bi ní ọjọ́ kèje oṣù karùn-ún 1975) jẹ́ olùtọ́nisọ́nà bọ́ọ̀lù-afẹsẹ̀gbá àti pé agbábọ́ọ̀lù agbedeméjì pápá-ìgbábọ́ọ̀lù ni tẹ́lẹ̀. Gẹ́gẹ́ bí i agbábọ́ọ̀lù ó ń ṣojú Avaldsnes IL lọ́wọ́lọ́wọ́, ọ̀kan lára ẹgbé bọ́ọ̀lù ìpín àkọ́kọ́ tó pinlẹ̀ sí etíkun ìwọ̀-oòrun Norway. Ó tún ti gbá bọ́ọ̀lù fún oríṣiríṣi àwọn ẹgbẹ́ bọ́ọ̀lù obìnrin tó dára jù lọ, ìyẹn Toppserien ti Norway, àti fún Linköpings FC pẹ̀lú QBIK ẹgbẹ́ bọ́ọ̀lù obìnrin Damallsvenskan ti Sweden.
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Maureen Nkeiruka Mmadu | ||
Ọjọ́ ìbí | 7 Oṣù Kàrún 1975 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Onitsha, Nàìjíríà | ||
Ìga | 1.78 m (5 ft 10 in) | ||
Playing position | Agbábọ́ọ̀lù ààrín pápá-ìgbábọ́bọ́ọ̀lù. | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Ado Babes | |||
Pelican Queens | |||
Jegede Babes | |||
IL Sandviken | |||
Klepp IL | |||
2006 | QBIK | ||
2007 | Linköpings FC | ||
2008 | Amazon Grimstad | ||
2010 | Kolbotn IL | ||
2011–2013 | Avaldsnes IL | ||
National team‡ | |||
1993–2011 | Nigeria women's national football team | 101 | |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Iṣẹ́ Àyànṣe rẹ̀
àtúnṣeMmadu ti gbá bọ́ọ̀lù fún Klepp IL ọ̀kan lára ẹgbẹ́ Toppserien ti Norway..[1] Bẹ́ẹ̀ ó tún ti gbá bọ́ọ̀lù fún Kolbotn ní Oslo, Norway, fún àkókò ti 2010, tí ó sì jẹ́ wí pé pèlú ìrànlọ́wọ́ rẹ̀ wọ́n gbé ipò kẹ̀ta ni Toppserien liìgì.[2] Ní ọjọ́ karùn-ún oṣù kejì 2012, ó gbá bọ́ọ̀lù fún Avaldsnes IL ní ifigbagbága tí kò pẹ̀lú ti àkókò náà ní Oslo.[3]
Iṣẹ́ rẹ̀ ní Ilẹ̀ Òkèrè.
àtúnṣeÓ jẹ́ ọ̀kan lára ẹgbẹ́ agbọ́ọ̀lù obìnrin ilẹ̀ Nàìjíríà, ó sì ti hàn ní ọgọ́rùn-ún ìgbà nínú àwọn eré bọ́ọ̀lù wọn,,[4] ó sì tún ti hàn nínú ìdíje bọ́ọ̀lù àwọn obìnrin ti gbogbo àwọn ìlú àgbááyé,[5] ó sì tún hàn nínú ìdíje àwọn eré-ìdárayá ìgbà-òòrùn ti ọdọdún mẹ́rinmẹ́rin ní 2000 àti 2004.[6]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Ikidi og Mmadu har riktige lønnsbet" (in Norwegian). NRK. 13 October 2005.
- ↑ 'I played for Nigeria while my mum died'
- ↑ Lyn-Avaldsnes Final 5 February 2012
- ↑ "FIFA Women's Century Club" (PDF). FIFA. 25 August 2009. Archived from the original (PDF) on 8 November 2012. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Maureen Mmadu - FIFA competition record
- ↑ "Maureen Mmadu Biography and Statistics". Sports Reference. Archived from the original on 2020-04-18. Retrieved 2009-10-14. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)