Maurice Wilkins
Maurice Hugh Frederick Wilkins CBE FRS (15 December 1916 – 5 October 2004) je omo New Zealand ara Ilegeesi asefisiksi ati asebioloji onihoro, ati elebun Nobel ti iwadi re ko ipa lori oye sayensi ita yanyan, iyasoto isotopu, iwokekere oloju ati X-ray diffraction, ati si idagbasoke radar. O gbajumo fun ise re ni King's College London lori igbamu DNA. Fun ise yi, ohun, Francis Crick ati James Watson gba Ebun Nobel fun Iwosan 1962, "fun iwari nipa igbamu onihoro awon onikikan nukleiki ati pataki re igberin ifitonileti ninu awon eroja alaaye."[1]
Maurice Wilkins | |
---|---|
Maurice Wilkins | |
Ìbí | Pongaroa, Wairarapa, New Zealand | 15 Oṣù Kejìlá 1916
Aláìsí | 5 October 2004 Blackheath, London, United Kingdom | (ọmọ ọdún 87)
Pápá | Physics, Molecular biology |
Ilé-ẹ̀kọ́ | University of California, Berkeley |
Ó gbajúmọ̀ fún | X-ray diffraction, DNA |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Nobel Prize in Physiology or Medicine (1962) |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ The Nobel Prize in Physiology or Medicine 1962. Nobel Prize Site for Nobel Prize in Physiology or Medicine 1962.