Mavis Dgajmah
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | ọjọ́ kọkànlélógún Oṣù kejìlá ọdún 1973 | ||
Playing position | Iwájú | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
La Ladies | |||
National team‡ | |||
Ghana | |||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Mavis Dgajmah tí a bí ní ọjọ́ kọkànlélógún Oṣù kejìlá ọdún 1973 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá ti àwọn obìnrin ọmọ orílẹ̀-ède Ghana kan tí ó mú ipò iwájú lórí pápá . Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá orílẹ̀-ède Ghana . Ó kópa nínú FIFA Women's World Cup ti ọdún 1999 àti ní FIFA World Cup Women ti ọdún 2003 . [1] Lórí ìpele ẹgbẹ́ ó ṣeré fún Ladies Ladies ní Ghana. [2]