Maximilian Carl Emil Weber (21 April 1864–14 June 1920) je onimo eto inawole ati onimo awujo omo ile Jẹ́mánì ti a mo gege bi okan ninu awon oludasile eko nipa awujo ati iseijoba igboro.

Max Weber
Ọjọ́ìbí(1864-04-21)21 Oṣù Kẹrin 1864
Erfurt, Prussian Saxony
Aláìsí14 June 1920(1920-06-14) (ọmọ ọdún 56)
Munich, Bavaria
Cause of deathPneumonia


Itokasi àtúnṣe