Maya Horgan Famodu jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà, tó jẹ́ oníṣòwò, àti olùdásílẹ̀ Ingressive.[1][2] Ó ṣèdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ kan tí orúkọ rẹ̀ n jẹ́ High Growth Africa Summit, àti Tech Meets Entertainment Summit.[3][4] Maya pẹ̀lú àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ (Sean Burrowes àti Blessing Abeng) tún ṣe ìdásílẹ̀ Ingressive for Good.[5][6]

Maya Horgan Famodu
woman speaking
Ní ọdún 2018
Ọjọ́ìbí24 Oṣù Kẹta 1991 (1991-03-24) (ọmọ ọdún 33)
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
American
Ẹ̀kọ́Pomona College
Cornell University
Iṣẹ́Entrepreneur

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Onyinye, Yvonne (9 October 2018). "Maya Horgan Famodu: On Self-Care And Courage". The Guardian. https://guardian.ng/life/maya-horgan-famodu-on-self-care-and-courage/. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  2. Udodiong, Inemesit (27 March 2019). "Meet the 10 inspiring women ruling Nigeria's tech ecosystem". Business Insider. Pulse. https://www.pulse.ng/bi/tech/meet-the-10-inspiring-women-ruling-nigerias-tech-ecosystem/9g5bg3l. 
  3. "Maya Horgan Famodu: Executive Profile & Biography - Bloomberg". www.bloomberg.com. Retrieved 2019-04-25. 
  4. Bella Naija (12 September 2018). "Venture Investor Maya Horgan Famodu of Ingressive is our #BellaNaijaWCW this Week". bellanaija.com. Retrieved 24 April 2019. 
  5. "How to Start a VC: Interview with Maya Horgan Famodu, Founder, Ingressive Capital". Forbes. 
  6. "Over 60,000 young Africans trained in Tech by Ingressive for Good, a year after launching". 13 September 2021.