Medgar Evers

Olóṣèlú

Medgar Wiley Evers (July 2, 1925 – June 12, 1963) je omo Afrika Amerika alakitiyan awon eto araalu lati Mississippi to kopa lati fopin si to eleyameya ni University of Mississippi. O di alakitiyan ninu egbe irinkankan fun awon eto araalu leyin igba to pada de ati ise oke okun ninu Ogun Agbaye 2k to si pari eko agba; o di akowe ori papa fun NAACP. O wo ise ologun ni odun 1943. Won yinbon fun un ni deede agogo kan ku ogun isegun loru ojo kejila, odun 1963 ni oju ona ile re jackson, Missisippi.

Medgar Wiley Evers
Medgar Evers.jpg
Ọjọ́ìbí(1925-07-02)Oṣù Keje 2, 1925
Decatur, Mississippi U.S.
AláìsíJune 12, 1963(1963-06-12) (ọmọ ọdún 37)
Jackson, Mississippi, U.S.
Iṣẹ́Civil rights activist
Olólùfẹ́Myrlie Evers-Williams 1951–1963 (his death)
Àwọn ọmọMeta
Parent(s)James Evers (father)[1]ItokasiÀtúnṣe

  1. per Charles Evers bio "Have no Fear" page 5