Medikal

Olórin ilẹ̀ Ghana

Samuel Adu Frimpong (tí wọ́n bí ní ọjọ́ karùn-ún oṣù Kẹrin, ọdún 1994), tí ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bí i Medikal, jẹ́ olórin ilẹ̀ Ghana tí wọ́n bí sínú ìdílè Portia Lamptey àti James Frimpong ní Sowutuom, ní Accra.[1][2]

Medikal
Orúkọ àbísọSamuel Adu Frimpong
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíiMDK, MedikalByK, Medikal
Ọjọ́ìbíApril 5, 1994
Accra, Ghana
Ìbẹ̀rẹ̀Sowutuom, Accra Ghana
AláìsíError: Need valid death date (first date): year, month, day
Irú orin
Occupation(s)
Years active2014–present
LabelsBeyond Kontrol
Associated acts

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Ó wá láti Sowutuom, ní Accra, Ghana. Medikal àti Sarkodie jẹ́ olórin tí wọ́n yàn jù lọ fún ìgba àmì-ẹ̀yẹ ní ọdún 2017 fún Ghana Music Awards. Ní ọdún 2018, ó farahàn lórí ètò Tim Westwood.[3][4][5] Medikal gba ẹ̀kọ́ girama rè ní Odorgonno Senior High. Òun ni ọmọ James Frimpong àti Portia Lamptey. Samuel mú Medikal gẹ́gẹ́ bí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ nítorí ó fẹ́ràn láti máa kọ orin nípa àọn oníṣègùn òyìnbó, àwọn oníṣẹ́-abẹ, ilé-ìwòsàn àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Kí ó tó bẹ̀rẹ̀ orin kíkọ, ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí i agbábọ́ọ̀lù fún Ghana Premier League, fún ọ̀wọ́ Sekondi Hasaacas. Látàrí iṣẹ́ ribiribi rẹ̀, ó ti di gbajúgbajà olórin. Yàtọ̀ sí pé wọ́n yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ ní ọdún 2017, ó gba àmì-ẹ̀yẹ MTN 4Syte Video ní ọdún 2016 fún fọ́nrán orin rẹ̀.[6]

Àwọn àwo-orin rẹ̀

àtúnṣe
  • Medikation (2013)[7]
  • Disturbation (2017)[8]
  • The Plug EP(2019)[9]
  • Island (2020)[7]
  • The Truth (2020)[10]

Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀

àtúnṣe
Ọdún Ilé-iṣẹ́ Olùgbà/Iṣẹ́ tí wọ́n yàn Àmì-ẹ̀yẹ Èsì Ìtọ́ka
2021 Vodafone Ghana Music Awards Himself Hiplife/Hip Hop Artist of the Year Gbàá [11]
La Hustle rmx ft Joey B and Criss Waddle Hip-Hop Song of the Year Wọ́n pèé
Himself Artist of the year Gbàá
3Music Awards Himself Artist (MVP) of the Year Wọ́n pèé [12][13]
La Hustle rmx ft Joey B and Criss Waddle Song of the Year Wọ́n pèé
Himself Hiplife/Hip hop Act of the Year Gbàá
La Hustle ft Joey B Hip Hop Song of the Year Wọ́n pèé
La Hustle rmx ft Joey B and Criss Waddle Best Collaboration of the Year Wọ́n pèé
Himself Rapper of the Year Wọ́n pèé
Himself Most Streamed Act of the Year Gbàá
4syte Music Video Awards 'Odo' ft. King Promise Best Male Video Wọ́n pèé [14]
La Hustle ft Joey B Best Edited Video Wọ́n pèé
Himself Most Influential Artist Gbàá
La Hustle rmx ft Joey B and Criss Waddle Big Tune Wọ́n pèé
La Hustle ft Joey B Most Popular Video Gbàá
'Nonsense' Best Hip Hop Video Wọ́n pèé
2020 Vodafone Ghana Music Awards Himself Hiplife/Hiphop Artist of the Year Gbàá [15]
"Omo Ada" Hip-life song of the Year Gbàá
2019 Vodafone Ghana Music Awards Himself Hip Hop Artist of the year Gbàá [16]
Himself Best Rapper of the year Gbàá
4syte Music Video Awards "Omo Ada" Best Special Effect Video Gbàá [17]
2017 Vodafone Ghana Music Awards Too Risky Afro Pop Song Of The Year Wọ́n pèé [18]
Confirm feat Sarkodie Hip Hop Song Of The Year Wọ́n pèé
Himself Hip-life/Hip Pop Artist Of The Year Wọ́n pèé
Himself Best New Act Wọ́n pèé
Himself Best Rapper of the year Wọ́n pèé
Confirm feat Sarkodie Best Collaboration of the year Wọ́n pèé
Himself Overall Artist of the year Wọ́n pèé
Exclusive Men of the Year Awards (EMY) Discovery of The Year Category Gbàá
African Muzik Magazine Awards (AFRIMMA) Best Newcomer Category Gbàá
2016 MTN 4Syte Music Video Awards Anthem Best Discovery Video Gbàá [19]

Àwọn àmì- ẹ̀yẹ 3Music

àtúnṣe

Ní oṣù Kẹta ọdún 2021, ó gba àmì-ẹ̀yẹ Hiplife/Hiphop Act of the Year ní 3Music Awards.[20]

Ní oṣù Kẹfà ọdún 2021, ó gba àmì-ẹ̀yẹ Hiplife/Hiphop Artist of the Year ní Vodafone Ghana Music Awards22.[21]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. name="Medikal">"Medikal". GhanaWeb. Retrieved 2020-11-23. 
  2. "Fella Makafui honours Nungua stool’s invitation, Chief gives new order". Citinewsroom - Comprehensive News in Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2024-05-25. Retrieved 2024-05-25. 
  3. "Sarkodie – Highest" (in en-US). Vibehubs.com. 2017-09-08. Archived from the original on 2018-02-21. https://web.archive.org/web/20180221161321/http://www.vibehubs.com/sarkodie-highest/. 
  4. "SEE FULL LIST OF NOMINEES – 2017 Vodafone Ghana Music Awards". 27 February 2017. Archived from the original on 24 April 2022. Retrieved 10 December 2024. 
  5. "The rise of AMG's Medikal". 12 November 2016. 
  6. "See complete list of winners" (in en-GH). Pulse Ghana. 2016-12-31. https://www.pulse.com.gh/lifestyle/events/2016-4syte-music-video-awards-see-complete-list-of-winners/k9wm5ce. 
  7. 7.0 7.1 "[MIXTAPE]: Medikal (MDK) Presents "Da Medikation"". Loud Sound Gh. Retrieved 17 February 2018. 
  8. "Medikal unveils tracklist for 'Disturbation'". 22 June 2017. 
  9. "Medikal Biography / Profile - Beatz Nation". 19 July 2019. 
  10. The Truth by Medikal (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì), archived from the original on 2021-07-11, retrieved 2021-07-05 
  11. "VGMA22: See the list of nominees - MyJoyOnline.com". Myjoyonline. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-25. 
  12. "3Music Awards 2021: All the winners". Music In Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-03-29. Retrieved 2021-06-27. 
  13. "3Music Awards 2021: Full list of winners - MyJoyOnline.com". Myjoyonline. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-27. 
  14. "Kuami Eugene, Adina, King Promise, others crowned winners at 2021 4Syte Music Video Awards - MyJoyOnline.com". Myjoyonline (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-27. 
  15. "Kuami Eugene wins VGMA Artiste of the Year 2020". MyJoyOnline.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-08-30. Retrieved 2020-08-30. 
  16. "2019 VGMAs: Full list of winners". GhanaWeb (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-05-19. Retrieved 2021-06-27. 
  17. "List of winners - MTN 4Syte TV Music Video Awards 2019". Ghana Music (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-11-16. Retrieved 2021-06-27. 
  18. "VGMA 2017: Medikal, Eugy, Ebony, Fancy Gadam Make Best New Act List". EOnlineGH.Com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-06-23. 
  19. "Full list of winners - MTN 4stye music video awards 2016". 2 January 2017. 
  20. "3Music Awards 2021: Full list of winners - MyJoyOnline.com". Myjoyonline (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-03-29. 
  21. "VGMA 22: Full list of winners". GhanaWeb (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-06-27. Archived from the original on 2021-06-28. Retrieved 2021-06-28.