Medina Deme Armino jẹ elere sisa ti ọna jinjin ti órilẹ ede Ethiopia. Ni ọdun 2019 ati 2020, Medina yege ninu Marathon ti Xiamen to waye ni Xiamen, China[1][2].

Medina Armino
Sport
Orílẹ̀-èdèEthiopia
Erẹ́ìdárayáAthletics
Event(s)Long-distance running

Àṣèyọri àtúnṣe

Ni ọdun 2019, Medina yege pẹlu wakati 2:27:25, Ni ọdun 2020, arabinrin gbiyanju lori wakati rẹ si 2:26:12.

Ni ọ̀dun 2018, Medina kopa to si yege ninu Marathon ti Treviso pẹlu wakati 2:33:17 ati Marathon ti Beirut pẹlu wakati 2:29:30[3][4].

Itọkasi àtúnṣe

  1. Medina Deme ARMINO Profile
  2. Xiamen Marathon title
  3. Treviso Marathon
  4. Beirut Marathon