Medina of Essaouira, tí a mọ̀ sí Mogador tẹ́lẹ̀ ni ó jẹ́ ìdá kan nínú ìdá mẹ́rin ìlú Medina tí ó wà ní Essaouira, ní orílẹ̀-èdè Morocco. Àjọ UNESCO sọ ibẹ̀ si ibi àbojúwò World Heritage Site ní ọdún 2001.[1]

Ìtàn àtúnṣe

Essaouira ni ó jẹ́ àpẹẹrẹ ìlú tí ó yàtọ̀ gidi láti òrùndún Kejìdínlógún tí wọ́n kọ́ pẹ̀lú ìlanà ìjẹ gaba àwọn ọmọ ogun àmúnisìn ṣe gbe kalẹ̀ ní apá àríwá Ilẹ̀ Adúláwọ̀. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ìpìlẹ̀ ìlú náà ni ó ti jẹ́ ojúkò okòwò orí omi tí ó so orílẹ̀-èdè Morocco àti àwọn ìyàngbẹ ilẹ̀ Saharan pẹ̀lú Yúróòpù ati gbogbo àgbáyé.[1]

Àwọn orísun àtúnṣe

Àdàkọ:Free-content attribution

ÀWọn ìtọ́ka sí àtúnṣe

  1. 1.0 1.1 Centre, UNESCO World Heritage. "Medina of Essaouira (formerly Mogador)". UNESCO World Heritage Centre (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-12-24.