Medina of Tetouan ni ó wà ní ara àwọn ìpín mẹ́rin ilẹ̀ Medina Tetouan ní orílẹ̀-èdè Morocco. Àjọ UNESCO sọ ibẹ̀ di World Heritage Site ní ọdún 1985.[1]

Ìtàn àtúnṣe

Tétouan ni ó jẹ́ ìkan nínú àwọn ìlú tó lààmì-laaka ní àsìkò ìpolongo ẹ̀sìn Mùsùlùmí, ìyẹn láti ọ̀rùndún kẹjọ sìwájù si. Ìlú yí jẹ́ ìlú tí ó so Morocco àti Andalusia pọ̀. Àwọn ọmọ bíbí Andalusia ni wọ́n tún ìlú náà gbé sókè lẹ́yìn tí wọ́n gba ìlú wọn padà lọ́wọ́ àwọn àmúnisìn Spain . Èyí ni a lè rí lára àwọn ìṣọwọ́ kọ́lé wọn tí ó fi hàn gbangba wípé wọ́n ti fìgbà kan wà lábẹ́ ìmúnisìn rí. Lóòtọ́ ni ìlú yí jẹ́ ìlú kékeré ní ẹkùn Medina, àmọ́ kò sí làbẹ́ ìmúnisìn kan kan mọ́ lẹ́yìn tí wọ́n ti gbàá padà. .[1]

Àwọn ẹ̀rí má a jẹ́mi nìṣó àtúnṣe

Àdàkọ:Free-content attribution

Àwọn ìtọ́ka sí àtúnṣe

  1. 1.0 1.1 Centre, UNESCO World Heritage. "Medina of Tétouan (formerly known as Titawin)". UNESCO World Heritage Centre (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-12-24.