Mekdes Bekele Tadese ni a bini ọjọ ogun, óṣu January, ọdun 1987 jẹ elere sisa lobinrin to da lori steeplechase ti ẹgbẹrun mẹta metres[1][2][3].

Mekdes Bekele at the 2012 Bislett Games. Photo: Chell Hill

Àṣèyọri

àtúnṣe

Ni ọdun 2006, Mekdes kopa ninu idije agbaye ti Junior ti Beijing China to si gba ipo kẹta ninu metres ti ẹgbẹrun mẹta[1]. Ni ọdun naa, Arabinrin naa yege ninu ere gbogbo ilẹ Afirica to waye ni Algiers, Algeria to si gbe ipo keji. Ni ọdun 2007, Mekdes kopa ninu idije agbaye to waye ni Osaka, Japan to si gbe ipo ogun. Ni ọdun 2008, Mekdes kopa ninu idije Ilẹ Afirica to waye ni Addis Ababa, Ethiopia to si gbe ipo keji. Ni ọdun 2010, Mekdes kopa ninu idije Ilẹ Afirica to waye ni Nairobi, Kenya ni bi to ti gbe ipo kẹfa. Ni ọdun 2012, Mekdes kopa ninu idije ilẹ Afirica to waye ni Porto Novo, Benin to si gbe ipo kẹrin.

Itọkasi

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 Mekdes BEKELE Profile
  2. Mekdes BEKELE
  3. Athletics 3000 m steeplechase W