Mellissa Akullu (tí wọ́n bí ní 25 August 1999) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù alájùsáwọ̀n ti ilẹ̀ Uganda. Ó kópa nínú ìdíje ti 2023 basketball season, ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn agbábọ́ọ̀lù alájùsáwọ̀n tó dára jù lọ.[4]

Mellissa Akullu
No. 15[1]Vanguard
Forward
Personal information
Born25 August 1999
NationalityUgandan
Listed height6 ft 1 in (1.85 m)
Career information
College
Career highlights and awards
  • GSAC Player of the Year (2024)[2]
  • GSAC Defensive Player of the Year (2024)[3]
  • NAIA All-American (2024)
  • WBCA Coaches’ All-American (2024)

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Melissa ní ìlú Kampala, Uganda.

Iṣẹ́ tó yàn láàyò

àtúnṣe

Ní oṣù kejì ọdún 2024, Golden State Athletic Conference pe Melissa ní agbábọ́ọ̀lù tó dára jù lọ ní ọ̀sẹ̀ náà (GSAC), níbi tí ó ti gba pọ́ìntì 23.5 àti àtúnṣe 19.0 fún ìjáwé olúborí ní Vanguard.[5]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. University, Vanguard (2024-02-28). "Akullu, Davis Earn Marquee Women’s Basketball Honors". Vanguard University. Retrieved 2024-03-19. 
  2. "Gazelles center Akullu named GSAC Player of the Year". MTN Sports. 2024-02-28. Retrieved 2024-03-19. 
  3. "Student Spotlight: Melissa Akullu '24". Vanguard University. 2023-04-17. Retrieved 2024-03-19. 
  4. "Melissa Akullu gets NAIA All-American nod". Bukedde. 2023-03-27. Retrieved 2024-03-19. 
  5. "Melissa Akullu (2/12/2024)". Golden State Athletic Conference. 2022-10-17. Retrieved 2024-03-19.