Mercy Achieng
Mercy Achieng jẹ agbọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 12, óṣu August ni ọdun 1992. Agbabọọlu naa ṣere fun Thika Queens ati team apapọ ilẹ kenya[1][2][3].
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Mercy Achieng Onyango | ||
Ọjọ́ ìbí | 12 Oṣù Kẹjọ 1992 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Kenya | ||
Playing position | Midfielder | ||
Club information | |||
Current club | Thika Queens FC | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Thika Queens FC | |||
National team | |||
Kenya women's national football team | |||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Àṣeyọri
àtúnṣe- Mercy kopa ninu Cup awọn obinrin ilẹ́ afirica ti agbaye, agbabọọlu na tun kopa ninu ere idije awọn obinrin COSAFA[4].