Meskerem Assefa
Meskerem Assefa Legesse Wondimagegn ni a bini ọjọ ogun, óṣu september, ọdun 1985 si Ilu Robe, Arsi jẹ elere sisa ti ọna jinjin. Meskerem ṣọju fun órilẹ ede Ethiopia ninu Olympics ti ọdun 2008 ati 2012[1][2].
Medal record | ||
---|---|---|
Women's Athletics (sport) | ||
Ó ṣojú fún Ethiopia | ||
African Championships in Athletics | ||
Fàdákà | 2008 African Championships in Athletics | 2008 Addis Ababa |
Àṣèyọri
àtúnṣeMeskerem kopa ninu idije agbaye lori ere sisa lẹẹmeji[3]. Meskerem bẹrẹ ere sisa ti arin ni ọdun 2001 Ni ọdun 2007, Meskerem kopa ninu ere gbogbo ilẹ Afirica nibi to gbe ipo kẹrin pẹlu ìṣẹju aya 4:09.83[4]. Ni ọdun 2009, Arabinrin naa kopa ninu idije agbaye ti ere sisa ninu abala akọkọ. Ni ọdun 2010, Assefa kopa ninu idije ilẹ afirica nibi to ti gbe ipo karun lori 1500m[5]. Ni ọdun 2011, Assefa kopa ninu ere gbogbo ilẹ afirica nibi to ti pari pẹlu ipo kẹrin. Ni ọdun 2012, Meskerem kopa ninu idije DècaNation nibi to ti pari pẹlu ipo keji. Ni ọdun 2013, Meskerem kopa ninu Marathon ti Houston nibi to ti pari pẹlu ipo kẹta ni wakati 2:25:17[6].