Mẹ́tàlì
(Àtúnjúwe láti Metal)
Mẹ́tàlì (láti Grííkì "μέταλλον" – métallon, "ìwalẹ̀"[1][2]) jẹ́ ẹ́límẹ̀ntì, àdàpọ̀, tàbí álọ́ì tó dára bíi hat is a good olùgbéwọra ìsètanná àti igbóná. Àwọn mẹ́tàlì únsábà jẹ́ títẹ̀rọ́, lílu wọ́n sí úndán.[3]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣeWikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Mẹ́tàlì |