Mítà

(Àtúnjúwe láti Metre)

Mítà je eyo tìpìlẹ̀ ìwọ̀n ìgùn ninu Sistemu Kakiriaye fun awon Eyo (SI).

Mítà.

Awon eyo mita ipin ati asodipupo ti a n lo ni wonyi:


Itokasi àtúnṣe