Mfon Sunday Udoka (tí a bí ní ọjọ́ kerin-dín-lógún, oṣù kẹfà ọdún 1976) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà-Amẹ́ríkà tẹ́lẹ̀rí agbábọ́ọ́lù inú agbọ̀n tí ó jẹ́ olùrànlọ́wọ́ olùkọni fún ẹgbẹ́ bọ́ọ́lù inú agbọ̀n ti àwọn obìnrin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, D'Tigress. Tí a bí ní Portland, Oregon, Udoka parí ilé-ìwé gíga Benson Polytechnic (1994) ní Portland ṣáájú kí ó tó lọ sí Ilé-ẹ̀kọ́ gíga DePaul ní Chicago, Illinois láti ọdún 1994 sí ọdún 1998. Ó jẹ́ ẹ̀gbọ́n sí olùkọni àti òṣèré NBA tẹ́lẹ̀ Ime Udoka. [1]

Mfon Udoka
Forward
Personal information
Born16 Oṣù Kẹfà 1976 (1976-06-16) (ọmọ ọdún 48)
Portland, Oregon, U.S.
NationalityAmerican / Nigerian
Listed height6 ft 0 in (1.83 m)
Listed weight187 lb (85 kg)
Career information
High schoolBenson (Portland, Oregon)
CollegeDePaul (1994–1998)
NBA draft1998 / Undrafted
Career history
1998Detroit Shock
2003Houston Comets
2004Los Angeles Sparks

Àwọn Ìtọ́ka Sí

àtúnṣe
  1. Ime Udoka profile hoopshype.com